Profile
Language Skills
YorubaNative
Lesson Feedback
Lesson history
| Last month | Last 3 months | All time | |
|---|---|---|---|
| Completed lessons | 0 | 0 | 0 |
| Attendance rate | 100% | 100% | 100% |
Teacher reviews
No record
Activities
- Mo fe latini akosile ede Yoruba ni ojoojumon. Loni mo fe ko aroko nipa ara mi (composition about myself). Oruko mi ni Ebunoluwa, mo je omo orile-ede Nijeriya. Won bi mi ni Nijeriya sugbon nigbati mo wa ni omo ikoko (kid) awon o bi mi gbe mi wa si orile ede Amerika. Mo ti dagba si orile ede Amerika. Mo n gbe ni ipinle erekushu Roode(Rhode Island). Erekushu Roode ni okere ju ninu gbogbo ipinle ti o wa ni orile ede Amerika. Awon ti o bi mi ko da gba ni Amerika da bi emi. Iya mi wa lati ipinle Ogun, baba mi wa lati ipinle Oyo. Mo feran awon to bi mi. Mo ni aburo kan, oruko re ni Oluwaseun. Omo odun mokanlelogun ni (21 years old). O dabo0 votedDecember 2, 20180
- Aworan yii fi iyara alarambara (exotic room) kan han, iyara naa si lewa gidigidi. Iyara yii ni aga ijoko meji, okan lara awon aga ijoko yii je aga oni timutimu (cushion chair). Awon aga yii je alawo pupa. Ibusun (bed) nla kan wa ninu iyara yii, otobi osi fe daada. Iyara na mo n toni toni (very clean) inu iyara naa si ni imole daada (the room is well lit) nitori ina merin ni o wa nibe. Ogiri (wall) iyara na dara pupu won si fi aworan inu patako (framed picture) ko si ara ogiri naa. Eniyan le wo ero amohunmaworan (television) nitoripe wa ni ibe paapa. Ibusun to wan be, mo le sun lori e, Ibusun titobi ni.0 votedDecember 2, 20180
- Omode obirin yii je omo kekere. Omo naa ko ju omo odun meta tabi merin lo. Omo naa ni ewa pupo. Omode obirin yii ni irun pupo ni ori, run naa si dudu o si n dan yoyo. Omo naa wo aso ti o ni awo repete. awo ti o wa ni ara aso omo kekere je awo pupa ati funfun at awo ewe. Mo feran aso re gan ni, nitori pe o baa lara mu. Omo naa dudu gan, eni keni ti o ba ni awo dudu ma n ni ewa pupo, nitori pe also dudu je arewa (black is beautiful?). Omo naa wo yeri eti (earring), Yeri eti naa si lewa gidigidi. Omobirin naa wo ade aya oba si ori. Mo fe fun omobirin yii oruko, oruko naa ni OmoShalewa.0 votedDecember 2, 20180

00:00
00:00