Describe the picture in Yoruba
Aworan yii fi a han iyara ni. iyara yii o ni aga meji. Aga je awo pupa. O da bi eeyan mu gbogbo iyara ki won to ya aworan. Ina merin o wan be ati aworan meji o wa lori wall. Eeyan o le wo Tv nitori pe tv wan be papa. Ibusun to wan be, mo le sun lori e, Ibusun o tobi gan ni.
Search from various English teachers...
Corrections · 1
1
Aworan yii fi iyara alarambara (exotic room) kan han, iyara naa si lewa gidigidi. Iyara yii ni aga ijoko meji, okan lara awon aga ijoko yii je aga oni timutimu (cushion chair). Awon aga yii je alawo pupa. Ibusun (bed) nla kan wa ninu iyara yii, otobi osi fe daada. Iyara na mo n toni toni (very clean) inu iyara naa si ni imole daada (the room is well lit) nitori ina merin ni o wa nibe. Ogiri (wall) iyara na dara pupu won si fi aworan inu patako (framed picture) ko si ara ogiri naa. Eniyan le wo ero amohunmaworan (television) nitoripe wa ni ibe paapa. Ibusun to wan be, mo le sun lori e, Ibusun titobi ni.
Want to progress faster?
Join this learning community and try out free exercises!
Don’t miss out on the opportunity to learn a language from the comfort of your own home. Browse our selection of experienced language tutors and enroll in your first lesson now!
Start Learning Today
