Search from various English teachers...
United States flagEbun
Describe the picture in Yoruba Obirin yii je omo kekere. Omo ko ju omo odun meta tabi merin lo. omo ni ewa to pupo. o ni irun to pupo papa. omo wo aso to ni awo repete. awo to wa ni aso omo kekere je awo pupa ati funfun at awo ewe. Mo feran aso re gan ni, nitori pe o da lori ara re. Omo dudu gan, eni keni to dudu won ma ni ewa to pupo, nitori pe dudu je lewa (black is beautiful?). Omo ni kankan lori eti re, mi o mo bawo nor se ma soro "earings" ni ede yoruba.omobirin ni ade l'ori re. Mo fe fun omobirin yii oruko. oruko mo fe fun re ni shalewa.

Corrections · 2

1
Omode obirin yii je omo kekere. Omo naa ko ju omo odun meta tabi merin lo. Omo naa ni ewa pupo. Omode obirin yii ni irun pupo ni ori, run naa si dudu o si n dan yoyo. Omo naa wo aso ti o ni awo repete. awo ti o wa ni ara aso omo kekere je awo pupa ati funfun at awo ewe. Mo feran aso re gan ni, nitori pe o baa lara mu. Omo naa dudu gan, eni keni ti o ba ni awo dudu ma n ni ewa pupo, nitori pe also dudu je arewa (black is beautiful?). Omo naa wo yeri eti (earring), Yeri eti naa si lewa gidigidi. Omobirin naa wo ade aya oba si ori. Mo fe fun omobirin yii oruko, oruko naa ni OmoShalewa.
0
Obirin ni omo kerere yii . Omo naa ko ju omo odun meta tabi merin lo. O ni ewa pupo. o ni irun pupo paapaa. Aso omo yi ni awo pupo. Awon awo naa ni awo funfun, awo pupa ati awo ewe. Mo feran aso re gan ni, nitori pe o dara ni ara re. Omo naa dudu bi koro isin, Awon eniyan dudu maa n ni ewa pupo nitori pe dudu duro fun ewa. Omo naa fi oruka eti si eti re. omobirin naa de ade. Mo fe fun omobirin yii ni oruko. Oruko ti mo fe fun ni shalewa.

Want to progress faster?

Join this learning community and try out free exercises!

Don’t miss out on the opportunity to learn a language from the comfort of your own home. Browse our selection of experienced language tutors and enroll in your first lesson now!

Start Learning Today