Search from various English teachers...
United States flagEbun
Notebook Entry 1 Mo fe lati ko Yoruba sile lojoumo. Loni mo fe salaye ara mi. Oruko mi ni Ebunoluwa, mo je omo orile-ede Nigeria. Won bi mi ni Nigeria sugbon nigbati mo n kere awon o bi mi gbe mi si America. Mo ti da gba ni America. Mo n gbe ni ipinle Rhode Island. Rhode island o ti kere ju gbgbo ipinle to wa ni America. Awon to bi mi ko da gba ni America da bi emi. Iya mi wa lati ipinle ougn. baba mi wa lati ipinle oyo. Mo feran awon to bi mi. Mo ni aburo kan. Oruko re ni oluwaseun. Omo odun 21 ni. O dabo

Corrections · 2

0
Mo fe latini akosile ede Yoruba ni ojoojumon. Loni mo fe ko aroko nipa ara mi (composition about myself). Oruko mi ni Ebunoluwa, mo je omo orile-ede Nijeriya. Won bi mi ni Nijeriya sugbon nigbati mo wa ni omo ikoko (kid) awon o bi mi gbe mi wa si orile ede Amerika. Mo ti dagba si orile ede Amerika. Mo n gbe ni ipinle erekushu Roode(Rhode Island). Erekushu Roode ni okere ju ninu gbogbo ipinle ti o wa ni orile ede Amerika. Awon ti o bi mi ko da gba ni Amerika da bi emi. Iya mi wa lati ipinle Ogun, baba mi wa lati ipinle Oyo. Mo feran awon to bi mi. Mo ni aburo kan, oruko re ni Oluwaseun. Omo odun mokanlelogun ni (21 years old). O dabo
0
I am going to do a 30-day challenge writing in Yoruba.

Want to progress faster?

Join this learning community and try out free exercises!

Don’t miss out on the opportunity to learn a language from the comfort of your own home. Browse our selection of experienced language tutors and enroll in your first lesson now!

Start Learning Today