Ó ba mi lẹru lati sọrọ niwaju awọn eniyan
Lọla mo ni lati sọrọ niwaju awọn akẹkọọ egbe mi ni Yunifasiti. Ó ba mi lẹru pupọ ṣugbọn mo n gbiyanju lati fi han awon eniyan wipe mo gbọ Yoruba. Mo nireti pe mo maa ṣe aṣeyóri ninu igbejade yii!