Ó da mi lẹru lati sọrọ niwaju awọn eniyan
Lọla mo ni lati sọrọ niwaju awọn akẹkọọ ni yunifasiti. Ó da mi lẹru pupọ ṣugbọn mo gbiyanju lati ma fi eniyan han pe mo n gbọn.
Mo nireti pe mo maa ṣe aṣeyóri ninu igbejade yii!
Search from various English teachers...
Corrections · 5
2
Ó ba mi lẹru lati sọrọ niwaju awọn eniyan
Lọla mo ni lati sọrọ niwaju awọn akẹkọọ egbe mi ni Yunifasiti. Ó ba mi lẹru pupọ ṣugbọn mo n gbiyanju lati fi han awon eniyan wipe mo gbọ Yoruba.
Mo nireti pe mo maa ṣe aṣeyóri ninu igbejade yii!
0
Ó da mi lẹru lati sọrọ niwaju awọn eniyan
Lọla mo ni lati sọrọ niwaju awọn akẹkọọ ni yunifasiti. Ó ba mi lẹru pupọ ṣugbọn mo ni lati gbiyanju lati maa fi han pe mo n gbọn.Mo nireti pe mo maa ṣe aṣeyóri ninu igbejade yii!
Want to progress faster?
Join this learning community and try out free exercises!
Don’t miss out on the opportunity to learn a language from the comfort of your own home. Browse our selection of experienced language tutors and enroll in your first lesson now!
Start Learning Today
