Bowo mo se ipese adiye lati jeun
Akoko, mo gbodo lo si oja lati ra adiye aye. Nigbati mo de ile, mo ma dubu adiye, leyin naa mo ma fi omi kana lati bo. Mo ma fi omi gbona lori adiye ti mo ku lati je pe mo le tu iye kuro si adiye. leyin naa mo ma ge adiye ke ke ke ati mo ma fi omi ati osan wewe lori adiye lati mu un. Nigba yii mo ma fi gbogbo ohun ipese lori adiye. Mo ma bo adiye ati din adiye. Nigba yii mo ti si obe, o ku lati fi adiye mo ti pese ninu obe. Ounje ti jina.
Search from various English teachers...
Corrections · 0
Don’t miss out on the opportunity to learn a language from the comfort of your own home. Browse our selection of experienced language tutors and enroll in your first lesson now!
Start Learning Today
